Eko Bibeli

Ekaabo!

Ni bi odun melo kan seyin mo bere si fura pe oluwa yio fe ki n ma ko awon eyan mi Eko Bibeli ni ede yoruba. A mo ni akoko na, nko ri idi to n o fise be. Oluko Bibeli nla kan nse daada pelu eleyi, mo ro wipe , kotun nilo ki emi na bere ohunkohun.
Sugbon ni odun ti o ko ja, ipe yi run pada wa, eleyi ti o wa lagbara ju ti ati eyin wa lo. Mo gbabgbo wipe oluwa gba mi laaye lati bere irin ajo igbagbo ninu ile ijosin yoruba, eleyi fun mi ni anfani lati ka Bibeli ni yoruba fun opolopo odun.
Olorun n fe ki gbogbo eniyan ko ni imo oro re denu denu, nitorina o ti gbe wa dide, pelu awon oluko miran lati ma ko Eko Bibeli ni yoruba. E le ma wo wa lori ero ahi lujara
Facebook: Adebayo Femi Ezekiel ati Femi Adebayo
YouTube: Olufemi Adebayo.
E se pupo.

Partner With Us

As you partner with us, we believe Christ’s Vision at Calvary to bring many sons into glory will find speedy fulfillment as we would do much more together than individually. Together we reach nations for the Lord and participate in the harvest that will user in His coming.